OBATALA (THE KING IN WHITE CLOTH) BY BABALAWO OBANIFA-Obanifa extreme documentaries(Vol 3)

   Click on the Vedio above to Watch and Download Young Jonn, Tiwa Savage - Let Them Know (Visualizer) ft. Joeboy
 OBATALA (THE KING IN WHITE CLOTH) BY BABALAWO OBANIFA-Obanifa extreme documentaries(Vol 3).                                    
OBATALA PRAISES
We have both short  and long praises that can be use to invoke Obatala . Below is the documentation of the two .
1.
OBATALA
Obatasa
Oba takun takun ti gbe ode iranje
Anire niwa
Aniwa nire
Oko abuke
Oko aro
Oko rara bori rekete
Oro Oko Afin
Afi ojo Gbogbo tobi
O tobi ko se gbe
Banta Banta ninu ala
Oba ala funfun gbo
O sun ninu ala
Oji ninu ala
O tinu ala dude
Babanla Oko yemoo
Ola  se e wo
Arugbo Ile Ifon
Afun  nini  gba  fun aini
O so  enikan  digba  Eni
Alagbede Orun
Monri Monri ti Monri  omo tuntun
Orisa to se oju to  se imu
Orisa alamon rere
Orisa Nla alamon iwa
Orisa Nla Alamo amonpin
Alabalase
Orisa gbingbinikin
Ali ma je nkan to legun
Orisa a  PA igbin  je  leyin ikarahun.
Translation
Obatala
Obatasa
The powerful king the reside in the town called Iranje
He that is in possession of blessings and good character
He as good character and at same time have blessings
Husband of hunch back
Husband of the cripple
You are the husband of dwarf woman with big flat head
The gnome the husband of albino
You leave  daily life in gorgeous beuty and greatness.
You mithyness is immense it can not be lifted
So immense in white apparel
One who sleep in white apparel
And wake up inside white apparel
Rises from glory to glory inside white apparel
Respected father husband of Yemoo
It pleasurable to see wealth
The oldest man of Ifon town
He who withdraw wealth from the person who have and give it to have- not

he who multiply a single person to many
The heavenly black Smith
The head moulder that mould babies head s
The diety that creates eyes and noses
The arch Divinity the owner of good clay
The arch Divinity the owner of good clay that is use to mould character
The arc Divinity the owner of good clay that is use to mould Destiny.
He has absolute power to make any thing he wants happen
A  very wealthy orisa.
the Divinity that wake up the doesn't eat any thing with bone

2.
Obatala
Obatasa
Oba takun takun ti gbe ode iranje
Anire niwa
Aniwa nire
Oko abuke
Oko aro
Oko rara bori rekete
Oro Oko Afin
Afi ojo Gbogbo tobi
O tobi ko se gbe
Banta Banta ninu ala
Oba ala funfun gbo
O sun ninu ala
Oji ninu ala
O tinu ala dude
Babanla Oko yemoo
Ola  se e wo
Arugbo Ile Ifon
Afun  nini  gba  fun aini
O so  enikan  digba  Eni
Alagbede Orun
Monri Monri ti Monri  omo tuntun
Orisa to se oju to  se imu
Orisa alamon rere
Orisa Nla alamon iwa
Orisa Nla Alamo amonpin
Alabalase
Orisa gbingbinikin
Ali ma je nkan to legun
Orisa a  PA igbin  je  leyin ikarahun.




Emo jii re lori itee

Afebojo awon jii re nisa re

Olua o wa jii re e

Agbe won ji taro taro

Aluko ji tosun tosun

Lekelekee; o jii re pelu ala funfun

Odidere toun tekoo

Obaala o jii re

Akuko gagara o jii re pelu agogo


Oosala o ji aboo ji ?


Abaala o jii re nile ifon

Akii je olodumare

Etu ji toun taaso

Obaala o jii re

Ahun ji tigba tigba

Igbin ji toun ti karahun

Oore o ji toun tipe e

Obaala o jii re e


Eja jii re ninu  ibu


Olua o wa jii re

Oka ji toro toro

Paramole ji toun tika

Oosala o ji tabi o ji

Ojola ji toun tohun

Irore toun teekanna

Asorin ji oloja igi

Olua o wa jii re

Anseke oloja eerun

Oosala o ji abo o ji




Obaala o jii re e

Okun ji oloja omi

Osa o ji oloja odo

 O o ji i re loni alaruwaye mi

Obaala o jii re e

Oni la mosin

Oosala pele alaase ola

Aji da gbedu lu fun

Obaala o jii re




Onile da lagba fun

Oba re tii gbele ifon

Olua o o wa jii re

Iwa oun aye

Ile oun orun

Baba o jii re e

Okunkun modi kanrun

Oosala o ji abo o ji

O sun lala o o bala je




O yi lala o o fara pa

Oosala o ja laja o o dala pa

Olua o o wa jii re e

Okunrin  moga moga ti nbe lode iranje

Ajokoo ma ni pekun

Kiribi lori bi i le oja

O ri rodo rodo bi olu ogan

 O ri gbon gbon ran gbongbonran

Oosala bi eni fi bon ti


Abewure rojo ibe lori

Ekun tii feranje ti kii se

Olowo mi aroo ko yeni

O daso da badii

O ji fuu we dodo

Iwo loba i wo loosa

Eni an ji se ni gbami ojumo mo

Eni an se ni gbami osan

La n se ni gbami ailele

Baba agba lo to se ni gbami oru


Alee i ba ota a

Aba i le se lohun

 N won lee won o baa

Afun ruru bi oye

O lo ni wa o loleyin bi agbara

Olua o wa jii re e

O de kan mop o

 O peepo agba ni yagbe

O bo mo lawo o da oju si

Baba maa roa





Okunrin rodo rodo bi olu ogan

Ogbogboo ilasa ewe gbogbo loje

Oju leyin akan

O yi mo lowo bi omi inu agbada

Aleegun lowo gbake

O fi ake dudu gbomo re kale

O fi emi ewure ra emi eeyan

Ni gba o ba buru

Erinlako ni fira emi mi

Arorun ma rinse lasaan


Tori abuke tori aro

Ni nse lo

Okiri magba toeun lo

Nibi rugudu, nibi regeja

Nifi gun ke onisegun

Ti tin a tun nasi

Baba o jii ree

Lilosun abomo mini jojo

Ite ti awon nte omo ilosun

Arodewogun taa loje te omo dagunro bee?


Ajagbo magbo leye

Ifa ti a n fa ijokun

Ero ijao ema fa keeke

Eni o fa keek’ obaala a tu i loju

A tu sii lenu

Baba nuu ifa t fa aguntan

Ero ijao ema fa ekun ni fon

Oju ekun ina, ina ni

Eyin ekun oorun

Eekanna ekun mewewaa


Igba owo ekun, o le somo logbe ori

Kan-an mo yan

Ogida ile, ijao oloola iju

Arodewogun toba ko dudu

A maa ko fun fun

O nkola lai yabe

Oosala tii kola laiko eje

Olube ikan abija sese

Ija akoni oro eleajewa

Oosala ni a ma jolube ikan


Eni o ba jolube ikan

Ata were lobaala fi ta mo loju

Ta mo lenu

Oro tii fay a ti foonu

O nyi mo nu bii baaka

Koku o je omo re oku

Korun o je omo re o run

Koje awure la o fi se gbe

Baba o ni jawa naa o fosi jeun

Obaala pele abagogo iran lapo

A ri masun masun bo le elenu


O fi agbada na bo owo eke

E we foosala; ko ma fagbaana bo owo iyaa mi

O ngbe nu gba

O nja mo ni ogun

Oporogodo aso ka dile

O so ipin onipin dipin

Obaala tii so olori buru di, olorii re

Ajalaye se benikan laa ko buruburu fun

Abi le loke ta I gbe nilee

Ile nbe lebaa orun

Ile seseefun


Ala lo e ko kaa merindinlogun

Alagbede orun

Iku ti nlu rin o now irin

O n tun irin ro

Abi ewiri ku bi ojo

Ewiri kan ndun huhu loju popo

Onigba nso iwarun

Iku ti I so ori oo titun


Odudu lObatala tii duri Elemere

Kori Elemere o ma ba a fo

Oosala du ri mi demi

Du ri mi demi ipee eye loko

Baba nuu akobale eye oba

Obanja won o sunlemo o dori odo

Lori odo emi iba makin

Ekun oko oyele

Oyele ijao n yele bo

Mo ri oni se e mi

Araa ifon won ni oko ni nro




Igba ti nwa roo

Ki i baa mu oko lowo

I baa moko asole lojo

I baa si moko ari osan lare

I baa si moko ari osan nijao

N won n sare won nka osan lojo

Won a posese ka san lare

Ijagudu lawon nka osan nijao

Sare o kaa osan lojo

Yara poseseka san lare

Mo fi ijagudu ba won ka san nijao


Odo ifon won o lare

Gbogbo won ni nsare yeetu yetu

Oosala lo meni ti o fosan le lowo

Emi ni o osan le lowo

Obaala a fun ni kun towo eni

Baba nuu kengbe sokun dooro deere lare

Kengbe dudu ori ope wonyi

Mo roni se mi

Iku lo mo hun ti nbe nibe

Ekee ifon won o gbodo memu

Ika won o yabe lare




Olomo ijao o nba won jijo le wa ajoopora

Aso pepipe to omo a ro bo ra

Omo Arara o le naro

Oosala ma se bayi nile awa

Merin losooro to se e bo

O fi kan woroko tele lare

Eyi to e gunle ni jao

N ni araa fon n dari jo bo

Okan rogbodo to e gunle lapa


O ya abitula

O ya mini mi, ni

O ya oka ninu oko

O ya ni pamole

Eyi woroko to e gunle niranje

Ti Iranje n lo ya digbin-ngbin

Ti Iranje igi hu igi o ni ewe

Araa fon won  ni igi oko se hewu ori gburu gburu

Oni sewe sewe iranje e

Ki won o ma se gbin-gbin


Baba gbin-gbin leewo be

Eyi o se gbin-gbin o ni wale

Kegi kegi iranje e

Ki won o ma ke gbin-gbin loko

Baba mi gbin-gbin leewo be

Ki lo se ti gbin-gbin o lewe

Araa fon nigi oko fi nhewu gburu gburu

Oku ilu gbin-gbin

Obaala mo ji yan moringbingbin

Mo te okuta moro sinkin


Mo te gbongbo ona mo rin gbingbin lawe

Ero iijao ara ilawe ile

Ni ilawe mo yara we

Mo mo roro bi gba elepo

Mo ji yan mo mori kefun

Baba mi mo deyin mo kosun re boosa

O ku ilu gbin-gbin

Obaala adikale eru apa

Ero ijao eku ilu Owowo

Araa fon a worin woowoo sebo


O ku ilu oyaya

Ti mo yaju ti mo ya enu

Oosala ekunigbin ku January araa fon o janu mo mi

Ti mo janu mo o

Eejanu ile yin san abi osan?

Epa ni sile etun kefun

E fi ototo eeyan soro lare

Ototo eeyan lee fi soro ni jao

Okiti kan baara o nbe nita asorin




Ti araa fon o gbodo gori e

Ero are o gebe

One ii gerebe lojo

Ebon i won mu onile se

Ajeji iii geebe lare

Arodewogun ebo laraa fon fi won se

Ologbon kii gerebe lojo

Ebo ni won mu ologboon se

Asi ere dani dani, ii gerebe ni iranje

Ebo laraa fon fi won se




Omotawede o gerebe lojo

Omotawede o wa gerebe ni ja o

Omotawede o wa gerebe ni Iranje

N won pe Adegbafo ooni

Ero ijao, n won pe adegbafo aborisa

N won pe ejeope oba lode adikun

Araa fon, won Akinnuu, omo afopa legun

N won ni, omotawede o gerebe lojo

Omotawede o wa gerebe ni ijao


Omotawede o wa gerebe ni Iranje

Akinnuu o ni iyan lo se debe

Iyan lo se de be

Ejoo ee je o maa lo

Akii mu omo ore bore

Iyan lo se debe iyaa Adikun un un

Iyan lo se debe, iya Otan leri

Are mi are

Ewaa mumi, dare e re mi

Emu mi defon e fun mi legun mu

Mi de lare mo yara are tete

Mo fi kainkain mo fi we lare



Ni lare mo te okuta moro sinkin

Eru o bami

Ti mo rawo lare

Are oosa, mo te okuta moro owobo

Ode are leeru gba aje

Omo afi wo dosu

Emaa rugba aje lo de baba mi

Oosala nib o ni un o daja si?

Ijao doja ifon wa dile


Ifon wa dile yeeni yeke

Ako eye ndaja ori igi

A gbi gbo o ba won koro de boosa

Oosala oloja tii da ifon

Akoda oni oja baba o un mi

Baba lobi ni tooto

Oja baba re ni

Omotawede oni ema ja soja mo

Oluufe ooni baba lobi

Oba leyo ajori baba lobi




Owarangun aga baba lobi

Ataoja lode o sogbo baba loni

O wa gba oja naa patapata

Oni eka lo  so de Asorin

Konikaluku o mo jot i e

Oosala ni ojo merin idun mu was aye

Omotawede ni a o sele moruko tojo je?

Oosala ni e mojo kan sose oun

Emu ojo kan sogun

Emu oojo kan se jakuta

Ojo kan yoku ni e mu sawo




Lonii ni won naja okun ileke

Ola ni won naja sehgi

Adabo Ireni ni won naja okun ni ifon

Ojo meriin oni won ana ti seseefun

Aja ti oje akesan o lojo

Yoo sele lojo

Onikaluku ni n fojo ti e naa

Lojojo a naja lare

N won n sapa bugaa buga a

Ijao a naja ao pon wo la

Nile oosala ni mo gbe jobe to di ototo mu

Mo le po ni le e


Mo je erinlako ni funfun

Ero ijao mo ko yo jatee

Mo leni nile mo sun leekan

Mo teni eekan sun bi eni n teni

Obaala ari koriko te omo toro finni

Nile oosala mo laso nile mo ro afon rodo

Afon laa ro rodo loganjo

Eegun nii ba ni lo

Eegu wa ni iwaju

Eegun wa leyin



Ori o gbodo wu

Bi ori ba wu ebo ni won fi ni se

Ema fi mi sebo temi o wuu

Ododo laa pakaja todo wale

Araa fon won leegun o ma mu lo

Ero iranje o gbodo lo aso pupa mo

O so araa fon di alaso funfun

Odo kan nbe ni iranje o gbe

Okan nbe ni ranje o gbe

Okan nbe niranje ko san

Okan son o la adikun ja


Okan son o topo lotun

Lonii un o podo baba wa loruko

Pasa tile son o la adikun ja

Odose odo owo

Ajeji adikun se bodo kodo ni

Pasa tile n won abu boju

Araa fon n won fi nweri

N won n sanra




Lo yoo asorin

Loyoo jingin-in bi eni gbowo ijo

Ayaba adikun won ee sese

Awon ero kodose won a ma so ose

Nigbati omotawede n rodo nijao

Pasatilee, aso funfun lo e leri aso funfun

Awon ero ibolo n rodo ni kodose

Kodose o de ni lorun ses mo rara

Pasatile sbi re o nse simi lenu


Ekuuyeeni kun kun

Omi kunkun omo tayaba laso

Opolo mesin adikun

Araa ilawe opa ni won nbu gburugbu loju omi

Obinrin o bopa ni lawe o mura

Omotawede o bopa ni lawa o mura

O mu opa je

O fi aita, o fi aira ta oja lopo


O gbe ologbe lakuko gba se ti e

Akuko adikun won o lee ba

O wa bepo satari osese

Baba nuu, osumore lona ego

Osumare adikun n won torun gbaja

Iku waye

Amule kan lee ogun

Afeyinkule ti le ogun gbongbon

Ero ijao n won kaso funfun won e leri

Aso funfun

Loni are re la nsaa




Osese re la npaa bo lona

Eni o duro n won dodo

Ei o bere won a dolo ilogi

Eni o rinna ijao won a di awurebe

Eni o sare n won dasaa

Obaala, lajo n wa kiri

Ade, ijao ilee

Ade, ife ooni

Oosala mo de ife ooye

Ade ijao adikun


Looto lade ijao aso rere

Oosala baba gberu kale

Abuke leyin aa pon-an si

Abuke ponmo kudu ke

Arara wewu gereje re boosa

Oni kinni mo wa se ni ta Asorin?

Moni baba ni mo wa

Oluufe ooni

Baba ni mo nwa kiri

Aweriba owo oje




Oloba obedu obaala,

Ayin kinni bomo lenu

Akandu sisi

Okan n so poun o mu po

Okan n so poun a mu eje

Okan nso poun a jori

Eyi to so poun amuje

N won a gboto to eeyanlade


Eyi ti nso poun a jori

N ni araa fon n fi erinlako bo

Baba ni mo wa wa

Akanfu sisi ti gbon mo lohun

Gbon-an gbon-an gbon

Baba ni mo wa wa

Oloro kase lenu

Abimo lesu ma ya

Baba ni mo wa wa

Oosala dakun ma bimi lesu


Ajagbo dakun ma besu lumi

Igba o se lede

Baba nu u

Oriri mori tii ba won gbegbo ageeje

Eyi onilu geeje geeje

Baba ni mo wa wa

Onilu geeje geeje

Baba ni mo wa wa

Onilu tai jo o





Onile won o gbodo jo

Ero ona won o yabe

Ayafi iku ti nbe lode orun

Afi oosa lawe

Afi olomo ti o lowo tii ba won jo agba a ii jo

Ilu taa mu awo arara se

Oosala onilu ti oni kokoro

Egigun abuke lafi lu ogidan fun baba

Eni to mu yin lajee oniro

Igba ori la fi mefun


Eje eeyan laa mu sun lare

Egigun eeyan la wa fi tepa osooro

Olua o wa jii re

Oosala o ji abi o jii

Obaala o jii re

Mo gbopi nifon

Mo gbo kara kuru leyin lekun

Bii ba segbe ole lare


Bi kii ba sole lojo

Ba defon taji niba seni

Emi o ni  ba won jole lojo

Un o si ni ba won jole ni jao

Ajini ba se lemi o se

Iku ti nbe lode orun

Ti se bi ojo mu ni lo

Orun mokandinlogun

Abiri nru iwa lapo


Sese ni se leyin aso dodo

Oloore abiyamo

Ekun ako ma ti ka leyin

Koye, kobo leyin

Mo roni se mi

Ara gbogbo ni fi gbo toloore

Egbe ni se leyin mi

A o mo eyi ti o se amodun

Alase faa bi na jo ni




Obatala pelee a to ko ni yungba

O kilo oro kan won o gba lapa

Ka soro fun ni ka mo gba

A maa dun ni titi

Oni sewe sewe ijao

E ma dapa se ewe mo

Bi o fe

Oko alapa ni o sinmi oko ewe sise mo


Segisegi iranje e!

Oni e ma dapa segi mo

Ore ode

Imule ode

Kii bode ja lapa

Arodewogun a re nii ba ode se

Igba ti o nba ode ja lapa

Aso ma ni baba e bora

O gboro kan, o jo muku muke


Okusu tii ba ode jagere lo oja

Mo roni se mi gege bi omo oloode

Olu koti okunrin

Iku tii ba ode pinwo ogboogba

Iku tii sode lofo afa

Ode mefa, o peta ninu won

O de  ji nigbekun lona apa

O ni oyo ku o rele loo wi

O ni o lo le lo ree ro

To ba dele ko wipe olori ode jako

Ija oosala soju mi un o dele wi


O wa boso sile loke apa

Araa le o gbodo ro oko

Ero oko o gbodo wale

Waa woo laja nke e!

Aja fi iboosi omo amotekun bonu

Waa woo ekun lo dara bayii

Ewa wo omo ekun tori minijo minijo

Ka san oke apa ti onigbanso lo ree ja

O nba onigba nso ja tapo torun


Tesin to be to o ti ida

Ase oro onigbanso o  muu

Arodewogun irin wewe nii fi legun

Abeti gbooro gbooro oran gbo

Alaso funfun ti n be lode ijao

O fapo ro sogbomosoo

O faso sile apekop

O fi aaja sile aaje

O binu pabuke je nilee olufon

Oosala o ji aboo ji?


Obaala o ku ojumo

Oosala duri mi de mi

Oko kukute

Oko ko olowo

Oko ko lese

Olua o wa jii re e

Onile aa lagba fun

Onipon gegebi koso irin

Okunrin gegeje bi eni lu iya ilu

Labalaba aboju lagbari.



TRANSLATION

Obatala
Obatasa
The powerful king that reside in the town called Iranje
He that is in possession of blessings and good character
He as good character and at same time have blessings
Husband of hunch back
Husband of the cripple
You are the husband of dwarf woman with big flat head
The gnome the husband of albino
You leave  daily life in gorgeous beuty and greatness.
You mithyness is immense it can not be lifted
So immense in white apparel
One who sleep in white apparel
And wake up inside white apparel
Rises from glory to glory inside white apparel
Respected father husband of Yemoo
It pleasurable to see wealth
The oldest man of Ifon town
He who withdraw wealth from the person who have and give it to have not
he who multiply a single person to many
The heavenly black Smith
The head moulder that mould babies head s
The diety that creates eyes and noses
The arch Divinity the owner of good clay
The arch Divinity the owner of good clay that is use to mould character
The arc Divinity the owner of good clay that is use to mould Destiny.
He has absolute power to make any thing he wants happen
A  very wealthy orisa.
the Divinity that wake up the doesn't eat any thing with bone

The Emon wake in its net

Afebojo woke up good in its hole

My lord I hope you rise up well

The Agbe woke up with indigo dye

Aluko woke up with his camwood

Buffbarcked woke up with his clean white clothe

Parrot with his red feather

Great king , you woke uup well

Cock rose up with his comb of fire on iit head

Oosala did you wake up or not?




Great king , did you wake well at Ifon?

Quinea fowl rose up with horn on its head

He who we greet and did not talk as Olodumare

The great king  did you wake up well?

The tortoise woke up with its shell

The snail rose up with  it shell

Great king did you wake up well?

The fish woke inside the river

My lord did you wake up well?

Oosala did you wake up or not?

Great king did you wake up well?

Ojola (python)wake up with it power

Irore woke with his claws

Asorin woke up ,the king among the trees

My lord you wake up well

The sea rise head of all the rivers

Did you wake up well today?

He who I carry from heaven to earth


Great king you wake woke up well today?

The owner of the house where we beat Agba

The good king who is leaving at Ifon

My lord you wake up well

Thw dead and earth

Soil and heaven

Father you woke up good

Darkness is high at heaven

Oosala did you woke up well?

You slept on white

You wrapped unpin white without injuries


You jump from the roof , you did not hurt your arm

My lord you rise up well

He who hangs white without removing it from heaven

A strong man in the city Iranje

He who sit without limit

All around us as the market square

As tall as strong, Oosala as we hang up the gun

He cursed the goat before beheading it

A leopard that kill animals without deny them

The great king with a gong of war



Obatala please ,he who have powerful bell in his sack

He put sleeplessness at home of liars

Please Oosala don’t put loss on my mother

His calabash worried them

He made some one with bad fate to become prosperious

The great king that makes bad luck to become good luck


He whose house no one can reach

The home near heaven

The house of white beads

He buikds a house with sixteen rooms

The mender of heaven

The death that molds new baby’s head


He-who cares for the head of abiku child

So that their heads may not get sick

Take care of my head for me

Father obanjala did not sleep on the floor

It is on the wood mortal

Leopard, husband of oyele

I saw my assistance

The oyele of ijao spread on the ground

The indigene of ifon said he is a farmer

If he is a farmer, did you find his hoe  in his hand?

Did he dig a ditch at ojo?

We saw orange at Are

We also found orange at Ijao

We ran to catch orange at Ojo




Walk slowly to catch the orange at Are

I fought hard to catch the orange at  Ijao

The youth atIfon have no elders

All of them ran fast

Only oosala knows those he will give orange

It is me, who he will give the orange

Great king, he who add to one  at  your hand

The liars at Ifon must not drink palm wine

The wicked one must not come there

The offsprijngs of Ijao dance an acient dance to vanish

A piece of cloth is enough for the son of cripple to be wrapped in


No way is the hunchback unble to stand up

Oosala please don’t act like this in our home

It is four among osooro that are good to worship

He stuck on one ground at Are

The one he stuck down at Ijao

That wasthe  one thst indigenes of ifon worshipped

The giany one that he stuck down at Apa

That one jad sixteen figures

It has fugures of cobra, viper and snakes

The longest one, he stuck to the soil at Iranje

That was the one that became gbin-in-gbin

Father, gbin-in-gbin is forgiven

The person that cut gbin-in-gbin will not survive it


Why gbin-in-gbin has no leaf?

The indigenes of Ifon say that the tree has grey hairs

Inhabitants of Ijao

Immigrants of Ilawe

At Ilawe, I quickly took a bath

And cleanse with a calabash of palm oil

I ate pounded yam

I painted my head white

My father, I later rubbed my body with camwood at the temple


You took human beings for sacrifice at Are

It is human beingd you took to make sacrifice at Ijao

There is a big heap of earth at outside of Asorin

That is forbiddeb for citizens at Ifon to climb

Inhabitants of Are must not climb it

Owner of the house must not climb

The visitors not climb the heap of earth at Are

Arodewogun, it is a sacrifice they would take him to make



Wise men do not climb the heap of eargh at Ijao

Sluggish and stupid person must not climb the heap of eartgh at Iranje

It is sacrifice they would take him to make

Only omotawede climbed the heap of earth at ojo

She climbed the heap of earth at Are

Omotawede also climbed the heap of earth at Iranje

Citizen of ijao invited adegbala aborisa

They also called ejeope the paramount ruker of adikun

The citizen of ifon called akinnuu

Offspring of he who took a stick to stop the war

They told them, omotawede climbed the heap of earth at ojo

She also climbed the heap of earth at ijao

Omotawede climbed the heap of earth at iranje

Akinnuu said she was just doing an exercise

She was only making  exercise, leave her alone

We should not take offsprings of soil to worship ore

She is only making exercise, mother adikun

Immigrant is my immigrant

You took me to Are


You love me

You took me to ifon

You make me drink egunb

I arrived at Are, I washed my calabash

I took a sponge of Are to bath

At ilare, I stepped on a stone

It sounded “sin kin”

I did noit hesitate

I saw skin at Are


I draw water to the house

It was at the shrine of oosa that I stepped on a stone

It sound “sin kin”

I did not fear

It was outside of are that I beat the calabash of the witch

The offspring of Afiwodosu

Omotawede don’t besat the calabash of the witch in our home




Oosala said, where should I establoish the market?

Ijao became the market

Ifon became home

Ifon is our abode

The male bird that played on a tree

Agbigbo did not follow them to bring wealth to the shrine of orisa

Orisalaa created tge market

Akoda said “it was my father’s market”

True, he is the son of the father

It was  his father’s market

Orisa started tto boast

They said it was my father’s market

They were all correct

They were the son of the father

Omotawede said don’t fight about market anymore

Oluife, he is a son of father


The monarch eleyo ajori

He is the son of the father

Ataoja he is the son of the father

Omotawede said, let us go to Asorin

Let everyone have their  own day

Oosala said, I only brought four days from heaven to the  earth

Omotawede said, how can we identify the names of the day?


Oosala said, take one day as my own week

Make another day jakuta

Take a day for ogun

The remaining day is for Awo

Today is the market day of okun bead

Tomorrow is market day for segi bead

The day after tomorrow is the market day of iyun at the city of ifon

The fourth day is market day of seseefun

The argument did not permit akesan to have a day

Everyone goes to market on his own day

They went to the market at ojo

They make their hard sound “bugabuga”




The day of market at Are

Their hands made a sound of “bugabuga”

At ijao market, we did not lick our palms

At house of ifon we lick our palms

The palm torn

At the home of orisaala

We ate soup with good taste

I have palm oil at home, ate snail in white

Indigene of ijao, I buy salt and I ate withiout salt


I have a mat at home

I slept on the grass

I prepared a mat as I made the mat

The great king that has grass to make bed for his children neatly

At the house of orisaala

I have clothes at home

I wrapped in Afon to go to the river

We wrapped them in Afon to go to the river at midnight

Egungun is following us

Mask informant

Masquerade at the back




One must not hesitate

He who hesitates

It is sacrifice they use them for

Don’t use me to make sacrifice

I did not hesitate

It is coloured clothes that you folded on your arms

From the river to the house

The indigene of ifon gave it to Egungun to carry home

Offspring of iranje; must not use red colour anymore,

That makes indigene of ifon to use white clothes


There is one river at iranje

Unable to dry up

There is one that did not run

There is one that runs all the way to the city of adikun

The one that goes to otun town

Today I will pronounce our father’s rivers name

Pasa was running from home to adikun town

Odose is a river of respect

The visitors of adikun think it was an ordinary river

Pasa river, they wash clothes and calabash


The indigenes of ijao came there to fetch water to drink

The iranje citizens came there to draw water to bath

The inhabitants of ibolo came there to wash their faces

The people of ifon came there and washed their heads

We are now happy at ojo, we dance

The ayaba of adikun did not make trouble

The visitors of kodose did not recognize the close of week


When omotawede went to the river at ijao

She was dressed up all in white

The visitors of ibolo went to the rivers at kodose

They were all dressed up in black

The torrent of rain of adikun must not see black clothes

They were clearing the gutter at Kodose

The river Kodose refused to expand

The river pasatile started running fast

The frog at adikun started to abuse them


The inhabitants of ilawe also abused opa

A woman must not abuse opa at ilawe without regret

Only father was the first experience

Omotawede abused opa at ilawe

She abused it and nothing happened

She did not sell, nor did she buy

She had many goods at the market

The cock at adikun is unable to fly

He had palm oil on his head

That is father

The rainbow at ego road


The rainbow at adikun came down from heaven with arms of death

The great king as fire, bite someone

He built a house near ogun’s shrine

He had a backyard very near ogun’s shrine

The citizens of ijao all dressed in white

Inhabitants of ifon wore a white robe

It is your race that we all started

It is your walk that we all walk on the road




Those who stand became wooden mortar

Those who squatted became grinding stone

Those who came from ifon road became awurebe

Those who ran became eagle

It is the great king that we all seek

We arrived at ijao house

We also went to ife ooni

Truly we at ijao asorere

Oosala we arrived at ife ooye

Oosala put his load down


The hunchback carried it on his own back

The dwarf wore oversized gown to the shrine

The albino did not ask

His eyes did not see clearly

Husband of cripple that mopped the floor and spoilt it with bottom

Old man respect to you

May you live long

Father take it easy

The monarch of Ife


I took straight way at Are

Oosala I arrived at the city of Asorin

Three stones at Asorin

The one knocked my toe

The one said “take it easy”

The one said when I did not know the road

What was my mission to Asorin?

I said, it was father I came to meet

The one who covered his head and hand with pewter

It is father I came to meet


Oloba obedu the greta king that gave little food to the mouth of baby

There is one akandu that said he want to lick palm oil

The one said, he wamted to drink blood

The  one said, he wanted to eat ori

The one said, he wanted palm oil

That was the one they worshipped with goat

The one that said he wanted blood

That was the one to receive human beings at ilawe

That one that said,

He wanted Eri

That was the one that indigenes of ifon worshipped with snails

It is father I came to meet

The one that made the voice of a child

It is father, I came to meet

The one who command in his mouth

It is father I came to meet

The strong one that made one meet esu without giving away




It is father I came to meet

Oosala please don’t push me to esu

Don’t push esu to me either

Celicular beans did not grow at ede

That is father

Orimori, the one that live at the forest of ageeje

He who had drum of geeje geeje

It is father I came to meet

The one who nhad drum that is forbidden for people to dance to


The visitor on the road must not come there

Only the death in heaven

Only orisa at ilawe

Only omotawede, she who danced to the agba that no one must dance to

Only masquerade in heaven

Only orisa at ilawe

Except the one who had no hand

Only the one who had no leg

The drum that we made of dwarf skin

The one who had command of skin of the cripple

Oosala who had the dtum without a key


The bone of abuke is the one we used to beat ogidan for the father

It  is the skull that we used to drink efun

It is human blood that we drank and slept at Are

It is human bone we used as walking stick

My lord did you wake up well?

I heard a noise at ifon

I heard a noise behind the door

If it is not a group of thieves at ojo

When we arrived at ifon

It will be those who come to sleep with a woman

I will not be among thieves at ojo


Also I will not be among the thieves at ijao

I preferred to be among those who come to sleep with a woman

The death at heaven that come to take people away

The sixteen heavens with different kind of deeds in a sack

Never turn his back from a faithful person kindness to the mothers

The leopard that refused to follow wicked people

He never left faithful people at once


My lord, my savior

Took all energy to serve kind people

He only blessed those people they punished

When they punished me

Father, please bless me

We don’t know what he is going to do next year

The instant vital forces as fire bite a person

Oosa olufon please you are the great

My lord, did you wake up well?

He gave a warning to indigenes of Apa

They neglected it

When we warn people and they don’t listen it pains me

He said, those who cut leaf at Ijao

Should not go to apa to cut leaf again

If they disobeyed, it is the grove of apa

That is going to stop it




He said, those who cut lumber at iranje

Should not go to apa to cut the lumber again

If they disobeyed, they are going to stop it at apa grove

Only hunter at apa said, they will always disobey.

The hunters at apa were very disobedient

The friends of hunters

A covenants friend of hunter

He must not fight with hunters of apa

When you fight with hunters of apa


You wore a jumper of fire you heard music to dance to okusu he who danced along with the hunters to the market

I saw my savior

Act as the son of the hunter

The death that shared money equally with hunter

He met six hunters

Killed three of them

He tied two to a pole

He told the last one to inform people

The leader of hunters was at the farm

He tripped at hill of Apa


The people at home must not go to the farm

The farmer was unable to come home

Come and see

The dog barks

The dog announces the spotted leopard

Come and see!

Beautiful leopard

The kasan leaf of apa hill that the calabash mender went to cut

He fought against calabash mender with a bow and arrow

With bow and knife and razor and sharp sword

The calabash mender had no poison

Arodewogun has a small iron to wage war


He who used wide ear to listen to every word!

He who used white robe lived at ijao

He took a bag to ogbomoso

He put his gown at apeko

He put his bell to ring at Aaje’s house

His aggression killed the hunchback at Olufon’s house

Obatala did you wake up or not

The great king, good morning

Oosala take good care of my head for me , husband of the short

Husband he who had no hands, no legs

My lord, did you wake up or not?

Butterfly with eyes on his back.

IMPORTANT NOTICE : As regards the article above, all rights reserved, no part of this article may be reproduced or duplicated in any form or by any means, electronic or mechanical including photocopying and recording or by any information storage or retrieval system without prior written permission From the copyright holder and the author Babalawo Obanifa, doing so is considered unlawful and will attract legal consequences

No comments:

Post a Comment

Note: Only a member of this blog may post a comment.

Featured post

Work-Life Balance - How to Protect Your Boundaries When Your Company Is Struggling - Sun and Planets Spirituality AYINRIN

 Work-Life Balance -  How to Protect Your Boundaries When Your Company Is Struggling - Sun and Planets Spirituality AYINRIN HBR Staff/Unspla...