Interpretation of sixteen major odu ifa (oju odu merindinlogun pt 5)posted by admin

This write up was compiled by omo Awo Rodriguez Ifatomi an ifa apprentice under the tutelage of babalawo Obanifa.
ODU IFA OSE MEJI :
 I I
II II
 I   I
 II  II
Ọsẹ Meji 1:

Ifa to wa nlẹ yii, Ọsẹ Meji lo wa nlẹ yii. Ifa sọ fun eleyii wipe ara ọrọọ [not confortable], ninu ipọnju lo wa. Ifa ni ko rubọ, Ifa ni yio ṣegun ti gbogbo ibi, iṣẹlẹ buruku ti n ṣẹlẹ si i, ainiṣiwaju, airitajeṣe, Ifa ni gbogbo ẹ yio dẹrọ [calm down]. Ti ayipada yio de ba a, ti o si ri ta jeṣe, loju Ọsẹ Meji. Bifa na fi sọ bẹẹ ni fun eleyii. O ni:Igba abidi jẹgi arugbo eti emi, atori abidi gbadagi a dia fun Ọrunmila, baba n ṣe awo rode Irọ. Ifa jẹ [ki] ara o rọ mi, akasu mẹfa nirọ fi rọ ni.Ọrunmila jẹ [ki] ara o rọ mi.Ifa lara o rọ eleyii ko rubọ nbẹ loju Ọsẹ Meji. Ifa…Ifa…Ifa ni o maa…ara maa rọ, ma ri ta je ṣe. Ọna rẹ maa la nbẹ. Ifa na sọ bẹẹ loju Ọsẹ Meji. Bẹẹ ni.
Ọsẹ Meji 2:
Ifa yii si tun sọ fun eleyii wipe, aarin ọta lo wa. Ko si rubọ, ko bọ ori rẹ. Ifa ni iṣẹgun o wa fun un. Gbogbo awọn tan ba ṣe ọta oun pata, Ifa lẹlẹda rẹ yio…yio…yio ṣe wọn ti o pa wọn jẹ danuni. Gbogbo awọn eni ti wọn ba ṣọta yio ku danu ni. Ifa un lo sọ bẹẹ. Enikan [k]ii ba babalawo ṣọta. Ifa ni keleyii ni obi, ko lobi lẹbọ nbẹ. Kan bapabi sifa nbẹ. Gbogbo awọn tan ba ṣọta, Ifa ni wọn o ku danu ni. Bẹẹ ni, Ifa sọ ninu Ọsẹ Meji. Nibi Ifa gba to fi sọ bẹẹ. O ni:Olori ni yanri, ogbẹri o gbọdọ gba obi pa lọ babalawo a difa fun Ọsẹ ti o ṣẹgun laiye ti o si ṣẹgun lajule ọrun.Wọn ni ki Ọsẹ Meji wọn ni… ko rubọ o. Aarin ọta lo wa. Lọsẹ Meji ba rubọ , lo ba ṣẹgun awọn ọta rẹ . Ni n ba jo, ni n ba n yọ. O ni bẹẹ babalawo toun [wi] bẹẹ, babalawo toun sọ.Olori ni yanri o, ogbẹri o gbọdọ gba obi pa lọwọ babalawo a difa fun Ọsẹ ti o ṣẹgun laiye ti o si ṣẹgun lajule ọrun. Ero Epo, ero Ọffa, ẹyin o rifa ọjọ bi ti n ṣẹ.Bi gbogbo awọn ọta ẹ ṣe ku nu un. Ifa ni eleyun yio ṣẹgun ọta. Gbogbo awọn ọta ẹ yio ku danu loju Ọsẹ Meji. Bẹẹ ni. Ifa sọ bẹẹ.
Ọsẹ Meji 3:
Ifa tun wa tẹ mọ eleyii leti, oun sọ fun eleyii, o laṣeyọri wa fun o. Ifa ni eleyii n travel lọ bi kan. O lọ ilu odikeji. O fẹ gbiyanju lo nipa ọrọ aje, nipa are gbogbo. Ifa ni ko ṣetutu, ko ma lọ. Ibi ton lọ yio gba a. Ti o dọlọla, ti o dẹlẹni, ti o donire gbogbo. To jẹ pe alejo o tun maa de ba, ti o lagbo gan, tagbo rẹ o fẹ. Ifa ni ko ṣetutu nbẹ. Bẹẹ ni loju Ọsẹ Meji. Ifa ti sọ bẹẹ fun eleyii, ko ma lọ, o ni [k]o ṣetutu. Bo ba jẹ pe oko waju lo n lọ, ko lọ, ko lọ mẹgan. Yio ṣaṣeyọri nbẹ. Yio da ile to lẹ, ti gbogbo eniyan maa… eniyan maa ba gbe. Ti o ba si jẹ pe company kan lo da silẹ, Ifa ni to ba ti daalẹ tan, yio yio loluranlọwọ nbẹ, ti gbogbo eniyan yio tun wa ran an lọwọ nbẹ. Ti o niyawo, ti o bimọ, ti o nire gbogbo, ti o gbọsin, ti o gbọra. Bẹẹ ni, Ọsẹ Meji lo sọ bẹẹ. Ifa na sọ pe:Olori ni yan ori, ogbẹri o gbọdọ gba obi pa lọwọ babalawo a difa fun Ọsẹ ni ọjọ ti n ṣe awo rode Ibadan.Wọn ni, ibi to n lọ…. yio si gbọsi, yio si gbọra, yio nire gbogbo. Ọsẹ Meji ba, lo ba ṣetutu, lo gbọna Ibadan. Bọsẹ Meji si gbọsi, to gbọra nu un. Lo labu [success], lo la yẹbyẹbẹ. Lọran ẹ gun, lo ko, ni n yin awọn awo, lawọn awo wa n yin Ifa. O ni bẹẹ, gẹgẹ ni babalawo toun wi, babalawo toun sọ.Olori ni yan ori, ogbẹri o gbọdọ gba obi pa lọwọ babalawo a difa fun Ọsẹ ni ọjọ ti n ṣe awo rode Ibadan. Ẹbọ ni wọn ni o ṣe, ero Epo, ero Ọffa, ẹ wa ba ni jẹbutu ire. Jẹbutu ire, la ba ni lẹsẹ ọbariṣa. Ero Epo, ero Ọffa, ẹ wa ba ni ni jẹbutu ọmọ, jẹbutu ọmọ, la ba ni lẹsẹ ọbariṣa. Jẹbutu aya, la ba ni lẹsẹ ọbariṣa.Ifa ni keleyun o rubọ; Ifa laṣeyọri wa fun un, ti o labu, ti o si sẹgun ọta rẹ. Bẹẹ ni Ifa sọ nu loju Ọsẹ Meji. Abọru aboye. Tifa na sọ nu
 TRANSLATION
Ọsẹ Meji 1:
The Ifa sign we have here is Ọsẹ Meji. Ifa says for this person that (s)he is not comfortable andin the middle of suffering. Ifa says (s)he should offer a sacrifice and that all of the terrible events that are happening to him/her, the lack of progress, lack of direction, etc. it will all calm down. A change will come, (s)he will know whatto do. This is what Ifa says in Ọsẹ Meji. Ifa says:Igba abidi jẹgi arugbo eti emi [shea butter], atori [whip] abidi gbadagi a dia fun Ọrunmila, baba n ṣe awo rode Irọ. Ifa jẹ [ki] ara o rọ mi, akasu mẹfa nirọ fi rọ ni. Ọrunmila jẹ [ki] ara o rọ mi.[Igba abidi jẹgi arugbo eti emi, atori abidi gbadagi cast Ifa for Ọrunmila when he was practicing Ifa in Irọ. Ifa do not let me be uncomfortable. One cannot be uncomfortable inabundance. Ọrunmila don’t let me be uncomfortable.]Ifa says this person will not be uncomfortable if(s)he will offer a sacrifice. Ifa says (s)he will find direction. His/her path will open up. Ifa says so in Ọsẹ Meji.
Ọsẹ Meji 2:
Ifa also says to this person that (s)he is in the midst of enemies. (S)He should offer a sacrificeand worship his/her destiny [ori]. Ifa says (s)he will achieve victory. Ifa says this person’s ori will get rid of all of those who chose to make him/her their enemy. All of those who are his/her enemies will be dealt with. Ifa says so. One does not make an enemy out of a babalawo. Ifa says this person include kola nutsin the sacrifice. We should consult Ifa with kola nuts. All those who make him/her their enemy will be dealt with. This is what Ifa says in Ọsẹ Meji. This is how Ifa said it. Ifa said:Olori ni yanri, ogbẹri o gbọdọ gba obi pa lọ babalawo a difa fun Ọsẹ ti o ṣẹgun laiye ti o si ṣẹgun lajule ọrun.[It is the leader who appoints, a novice cannot take kola nuts from a babalawo cast Ifa for Ọsẹ who gained victory on earth and heaven above.]Ọsẹ Meji was told to offer a sacrifice because he was surrounded by enemies. Ọsẹ Meji did ashe was instructed and defeated all of his enemies. He danced and rejoiced. He said told him so, the babalawo said so.Olori ni yanri o, ogbẹri o gbọdọ gba obi pa lọwọ babalawo a difa fun Ọsẹ ti o ṣẹgun laiye ti o si ṣẹgun lajule ọrun. Ero Epo, ero Ọffa, ẹyin o rifa ọjọ bi ti n ṣẹ.[It is the leader who appoints, a novice cannot take kola nuts from a babalawo cast Ifa for Ọsẹ who gained victory on earth and heaven above. People from near and far, don’t you see how Ifa’s predictions have come true?]That is how all of Ọsẹ Meji’s enemies died. Ifa says this person will defeat his/her enemies, they will be severely defeated in Ọsẹ Meji. This is what Ifa says.
Ọsẹ Meji 3:
Ifa also advises this person that success lies ahead. Ifa says this person is traveling somewhere. (S)He is going to another country. (S)He wants to try doing business there. Ifa says (s)he should offer a sacrifice and go to that place. The place where (s)he wants to go will be favorable. (S)He will become wealthy, important, and have many blessings. If it is a stranger, (s)he will have a large entourage that will constantly grow. Ifa says (s)he should offer a sacrifice. This is what Ifa says in Ọsẹ Meji. Ifa said that this person should go and offer a sacrifice. If it is a far away place, (s)he should go and look for a farmland. Success is in store for this person. (S)He will build a settlement, many people will come to live there. If (s)he wants to build a company, Ifa says when (s)he is finished, (s)he will find a helper, and people will surely come to assist him/her. (S)He will gain wives, children, blessings, and be prosperous and successful. Yes, Ọsẹ Meji says so. Ifa says:Olori ni yan ori, ogbẹri o gbọdọ gba obi pa lọwọ babalawo a difa fun Ọsẹ ni ọjọ ti n ṣe awo rode Ibadan.[It is the leader who appoints, a novice cannot take kola nuts from a babalawo cast Ifa for Ọsẹ when he went to practice Ifa in Ibadan.]He was told that he would prosper and be successful in the place where he was is going. Ọsẹ Meji offered the sacrifice and took the roadto Ibadan. That is how Ọsẹ Meji prospered and became successful. He became incredibly successful. His problem was resolved, and everything fell into place. He praised his babalawo, and the babalawo in turn praised Ifa. He said, “It is how my babalawo told me, my babalawo said it would be so.”Olori ni yan ori, ogbẹri o gbọdọ gba obi pa lọwọ babalawo a difa fun Ọsẹ ni ọjọ ti n ṣe awo rode Ibadan. Ẹbọ ni wọn ni o ṣe, ero Epo, ero Ọffa, ẹ wa ba ni jẹbutu ire. Jẹbutu ire, la ba ni lẹsẹ ọbariṣa. Ero Epo, ero Ọffa, ẹ wa ba ni ni jẹbutu ọmọ, jẹbutu ọmọ, la ba ni lẹsẹ ọbariṣa. Jẹbutu aya, la ba ni lẹsẹ ọbariṣa.[It is the leader who appoints, a novice cannot take kola nuts from a babalawo cast Ifa for Ọsẹ when he went to practice Ifa in Ibadan. He did everything asked of him. People from far and near, come meet me in the midst of children, wereceive the blessing of children at the feet of God. We receive the blessing of wives at the feet of God.]Ifa says this person should offer a sacrifice. Success lies ahead of him/her, and (s)he will become successful and defeat his/her enemies. This is what Ifa says in Ọsẹ Meji.
ODU IFA OFUN MEJI
  II  II
   I   I
  II  II
   I   I
Ofun Meji 1:
Ifa yii, Ifa Ọrangun Meji. Eni ta ba…to jade si, Ifa sọ fun eleyii wipe, laarin ọta lo wa o. Ko rubọ, kole ba ṣẹgun o. Ifa ni yio ṣẹgun, to ba ti le rubọ o. Ifa laṣeyọri o si wa fun un. Ifa lọran rẹ o wa gun, ti o ko. Eni tifa yi jade si, loju Ọrangun Meji. Ifa tisọ fun un. Ifa ni ko ma si ni ahun. Ko ma…ko ma… kako yawọ. To ba ni owo, ko fun eniyan. Ko… ko ma dash eniyan ni nkan. Ifa ni… ni… ni yio mu ko ṣẹgun. Ko ma ma di ọwọ kan. Ko ma ṣe fun eniyan. If he have something, he can do for another person, because of that, he [will] save himself [from] enemies. Ifa ni ko… ko… ko kako yawọ. Ifa ni yio ma ṣẹgun ọta. Bẹẹ ni. Nibi Ifa gba to fi sọ bẹẹ. O ni:Ifa nla la nla fi gbafa nla n la, oogun nla nla laa figba oogun la nla. Ẹgbasere laa fi tanran Sere. Igba ta a ba ri Sere mọ, emi la fi tanran ẹ gba a, a difa fun Olokun nijọ ti ẹri gbogbo n ba ṣọta.Olokun re gbogbo ẹri, gbogbo odo patapata, nanba ṣọta. Ah! Bo duro nibi kan, ko ni mọọ ṣe loju wọn . Wọn o gba tiẹ rara. Ah! O wa meji kẹta, o darunun. Lo ba gboko awo lọ. O sọrọ si pe… Njẹ oun le bọ ninu iṣoro toun ni. Gbogbo awọn tan boun ṣe ọta yii. Lo dafa si. Ọrunmila sọ fun un, oni, ninu ohun teleyii dafa si o le bọnu iṣoroyii, leleyii dafa si. Gbogbo awọn tan boun ṣọta yii, oun o ṣẹgun wọn, ti wọn di ọba le oun lori bi. Ọrunmila ni to dafa si nu un; Olokun ni bẹẹ ni. Ah, Ọrunmila ni ko rubọ. O ni ko ni iya ewurẹ mẹrin lẹbọ. Ko ni ọpọ aṣọ, ko ni ọpọlọpọ owo, kolọpọlọpọ obi. Ifa ni to ba ti ṣe gbogbo yii letutu, oni yio di ọba le gbogbo awọn tan ba ṣọta lori.Olokun, o ma rubọ ọ. O gbọ riru, o ru. Olokun gbọ titu, o tu. O gbọ atete ha ẹbọ kẹrẹkẹ loju ọpọn, o ha. Ijo ni wa n jo, ayọ ni n yọ. Nigba to ṣẹgun tan, ti gbogbo awọn ẹri yio ku, na ba… na ba wa… na ba wa ba. Ah, Olokun, ẹ dabo o. Awa o ba yin ṣọta mọ o. Ẹ jọ, ẹ foriji wa o. Gbogbo eniyan f… na n tọrọ aforiji. Nan wa sọdọ rẹ, gbogbo odo patapata, na ba pejọ. Nan tọrọ aforiji lọdọ rẹ. Ni Olokun naa ni, oun o binu si yin. Ko si ibinu kankan. Gbogbo yin, ẹyin lẹ n binu si mi. Ẹyin lẹ ba mi ja, ẹyin lẹ n ba mi ṣọta. Oun o binu u. Ni Olokun ba, lo ba ni yin awọn awo rẹ tan sọ fun un pe yio ṣẹgun. Lo wa yin awọn awo, lawọn awo rẹ naa wa n yin Ifa. O ni bẹẹ babalawo toun [wi] bẹẹ, babalawo toun sọ:Ifa nla la nla fi gbafa nla n la, oogun nla nla laa figba oogun la nla. Ẹgbasere laa fi tanran Sere. Igba ta a ba ri Sere mọ, emi la fi tanran ẹ gba a, a difa fun Olokun nijọ ti ẹri gbogbo n ba ṣọta.O ṣe bọwọ fun Olokun, omi mo gbọẸ bọwọ fun Olokun.Olokun lagba omi.Olokun lagba omi, Olokun lagba omi.Ẹri gbogbo, ẹri gbogbo ẹ bọwọ fun Olokun.Olokun lagba omi.Olokun lagba omi, Olokun lagba omi.Ẹri gbogbo ẹ bọwọ fun Olokun.Olokun lagba omi.Bi Olokun ṣe je agba omi titi doni. O jẹ olori omi patapata. Lati igba naa ni gbogbo odo patapata ti n fori balẹ fun Olokun. Pe oun lọga awọn. Ifa ni eleyii ko rubọ. Yio dọga le gbogbo awọn tan ba ṣọta lori, patapata. T… t… Tan si gba poun gan laṣaju. Bo ba jẹ pe eleyii ganan, oun di jẹ to wa jẹ oloṣe ilu ni. If it is a politician. To si fẹ dipokan mu. Ifa ni ko ṣetutu. Gbogbo awọn ti wọn dile gbe mọ, pe wọn o ni ji o ṣe. Ifa ni gbogbo wọn patapata, ni o ṣẹgun wọn tan si to wa ma bẹ ẹ. Poun ni ọga wọn. Bẹẹ ni, Ifa sọ bẹẹ. Bo ṣe gọmina lo fẹ ṣe o, bo ṣe sẹnator lo fẹ ṣe o, bo ṣe rẹpu… house of rep lo fẹ ṣe o. Ifa pe… yio ṣẹgun wọn gbogbo wọn patapata. Bẹẹ ni Ifa sọ. Loju Ọrangun Meji. Bẹẹ niOfun Meji 1:Ifa yii, Ifa Ọrangun Meji. Eni ta ba…to jade si, Ifa sọ fun eleyii wipe, laarin ọta lo wa o. Ko rubọ, kole ba ṣẹgun o. Ifa ni yio ṣẹgun, to ba ti le rubọ o. Ifa laṣeyọri o si wa fun un. Ifa lọran rẹ o wa gun, ti o ko. Eni tifa yi jade si, loju Ọrangun Meji. Ifa tisọ fun un. Ifa ni ko ma si ni ahun. Ko ma…ko ma… kako yawọ. To ba ni owo, ko fun eniyan. Ko… ko ma dash eniyan ni nkan. Ifa ni… ni… ni yio mu ko ṣẹgun. Ko ma ma di ọwọ kan. Ko ma ṣe fun eniyan. If he have something, he can do for another person, because of that, he [will] save himself [from] enemies. Ifa ni ko… ko… ko kako yawọ. Ifa ni yio ma ṣẹgun ọta. Bẹẹ ni. Nibi Ifa gba to fi sọ bẹẹ. O ni:Ifa nla la nla fi gbafa nla n la, oogun nla nla laa figba oogun la nla. Ẹgbasere laa fi tanran Sere. Igba ta a ba ri Sere mọ, emi la fi tanran ẹ gba a, a difa fun Olokun nijọ ti ẹri gbogbo n ba ṣọta.Olokun re gbogbo ẹri, gbogbo odo patapata, nanba ṣọta. Ah! Bo duro nibi kan, ko ni mọọ ṣe loju wọn . Wọn o gba tiẹ rara. Ah! O wa meji kẹta, o darunun. Lo ba gboko awo lọ. O sọrọ si pe… Njẹ oun le bọ ninu iṣoro toun ni. Gbogbo awọn tan boun ṣe ọta yii. Lo dafa si. Ọrunmila sọ fun un, oni, ninu ohun teleyii dafa si o le bọnu iṣoroyii, leleyii dafa si. Gbogbo awọn tan boun ṣọta yii, oun o ṣẹgun wọn, ti wọn di ọba le oun lori bi. Ọrunmila ni to dafa si nu un; Olokun ni bẹẹ ni. Ah, Ọrunmila ni ko rubọ. O ni ko ni iya ewurẹ mẹrin lẹbọ. Ko ni ọpọ aṣọ, ko ni ọpọlọpọ owo, kolọpọlọpọ obi. Ifa ni to ba ti ṣe gbogbo yii letutu, oni yio di ọba le gbogbo awọn tan ba ṣọta lori.Olokun, o ma rubọ ọ. O gbọ riru, o ru. Olokun gbọ titu, o tu. O gbọ atete ha ẹbọ kẹrẹkẹ loju ọpọn, o ha. Ijo ni wa n jo, ayọ ni n yọ. Nigba to ṣẹgun tan, ti gbogbo awọn ẹri yio ku, na ba… na ba wa… na ba wa ba. Ah, Olokun, ẹ dabo o. Awa o ba yin ṣọta mọ o. Ẹ jọ, ẹ foriji wa o. Gbogbo eniyan f… na n tọrọ aforiji. Nan wa sọdọ rẹ, gbogbo odo patapata, na ba pejọ. Nan tọrọ aforiji lọdọ rẹ. Ni Olokun naa ni, oun o binu si yin. Ko si ibinu kankan. Gbogbo yin, ẹyin lẹ n binu si mi. Ẹyin lẹ ba mi ja, ẹyin lẹ n ba mi ṣọta. Oun o binu u. Ni Olokun ba, lo ba ni yin awọn awo rẹ tan sọ fun un pe yio ṣẹgun. Lo wa yin awọn awo, lawọn awo rẹ naa wa n yin Ifa. O ni bẹẹ babalawo toun [wi] bẹẹ, babalawo toun sọ:Ifa nla la nla fi gbafa nla n la, oogun nla nla laa figba oogun la nla. Ẹgbasere laa fi tanran Sere. Igba ta a ba ri Sere mọ, emi la fi tanran ẹ gba a, a difa fun Olokun nijọ ti ẹri gbogbo n ba ṣọta.O ṣe bọwọ fun Olokun, omi mo gbọẸ bọwọ fun Olokun.Olokun lagba omi.Olokun lagba omi, Olokun lagba omi.Ẹri gbogbo, ẹri gbogbo ẹ bọwọ fun Olokun.Olokun lagba omi.Olokun lagba omi, Olokun lagba omi.Ẹri gbogbo ẹ bọwọ fun Olokun.Olokun lagba omi.Bi Olokun ṣe je agba omi titi doni. O jẹ olori omi patapata. Lati igba naa ni gbogbo odo patapata ti n fori balẹ fun Olokun. Pe oun lọga awọn. Ifa ni eleyii ko rubọ. Yio dọga le gbogbo awọn tan ba ṣọta lori, patapata. T… t… Tan si gba poun gan laṣaju. Bo ba jẹ pe eleyii ganan, oun di jẹ to wa jẹ oloṣe ilu ni. If it is a politician. To si fẹ dipokan mu. Ifa ni ko ṣetutu. Gbogbo awọn ti wọn dile gbe mọ, pe wọn o ni ji o ṣe. Ifa ni gbogbo wọn patapata, ni o ṣẹgun wọn tan si to wa ma bẹ ẹ. Poun ni ọga wọn. Bẹẹ ni, Ifa sọ bẹẹ. Bo ṣe gọmina lo fẹ ṣe o, bo ṣe sẹnator lo fẹ ṣe o, bo ṣe rẹpu… house of rep lo fẹ ṣe o. Ifa pe… yio ṣẹgun wọn gbogbo wọn patapata. Bẹẹ ni Ifa sọ. Loju Ọrangun Meji. Bẹẹ ni.Ọrangun Meji 2:Ifa tun sọ fun eleyii, loju Ọrangun Meji [ba mi tilẹkun. Ah ah.] Ifa tun sọ fun eleyun loju Ọrangun Meji, Ifa ni ọran rẹ, yio gun, yio ko. Ifa ni, iṣẹgun n bẹ fun eleyii. Keleyii wa ṣọra. Ko ma siwa hu. Ko ṣọra, nitoripe eni to ba ti daa, ọran rẹ yio fadura. Ẹ n ti o da, ọran rẹ fadura. Keleyii oṣọra, ko ṣọ liẹtẹ. Ko ma ba ja sọfin aiye. Ko ma pe boun ṣe tore. Tori pe ẹ n ba ro pe bo n ṣe tore, anytime o le jabọ, ko dẹni lẹlẹ [that person becomes nothing]. Ifa na lọ sọ bẹẹ. Ifa ni ṣugbọn, teleyii ba ti ṣọra, to si mura ṣadura, tawọn babalawo si jawe Ifa fun un, Ifa ni iṣẹgun de. Bẹẹ ni, ibi Ifa un gba to fi sọ bẹẹ re o. O ni:Bi igi ba da, igi a yẹri, bi eniyan ba ku, a ku eniyan sa sa sa nilẹ. Bi eni ori eni ba ku, eni ilẹ le a si di eni ori eni a difa fun Araba pataki eyi ti o kẹhin igi loko.Wọn ni ki Araba, wọn ni o rubọ. Aarin ọta lo wa. Wọn mura ti ṣe ku pa papa ni. Laraba ba mọ, o gbọ riru, o ru. O ma gbọ titu, o tu. Iṣẹgun ba de. Laraba ba ṣẹgun, lo ṣẹgun, lo ba bori gbogbo wọn. Lo ni, ah , awọn babalawo tan dafa fun oun, o gbọdọ yin wọn. Lo ba sọ fun awọn awo rẹ. Lo lọ dupẹ. Nawọn awo naa, obi to mu wa sọdọ awo, awo naa mu lọ nifa. Na nan ba n jo, nan yọ. O ni bẹẹ babalawo toun [wi] bẹẹ, babalawo toun sọ.Bi igi ba da, igi aiye ri, bi eniyan ba ku, a pe eniyan sa sa sa nilẹ. Bi eni ori eni ba ku, eni ilẹ le a si di eni ori eni a difa fun Araba pataki eyi ti o kẹhin igi loko. Ẹbọ ni wọn ni ko ṣe, o si gbe ẹbọ nibẹ, o rubọ. Riru ẹbọ ni fi ti gbe ni. Aitete ruteṣu a da ladanu. Ko pẹ, ko jinna, Ifa wa ba ni la rin iṣẹgun, a rin iṣẹgun la ba ni lẹsẹ ọbariṣa.Oun ṣe: Kowo, kowo, Araba o wo mọ.Oju tiroko. Ko kukuku mọ o, otoṣi o ku mọ. Oju tọ lọrọ. Bi aiṣaiku sawo, ka ṣaiku sin awo, eniyanti n bawo yan odi.Ka ṣaiku sawo…Ifa ni gbogbo eni ba ba eleyun ṣọta patapata, ni o ku danu patapata. Teleyun o si depo ibi ti n lọ, ti o dolori le wọn lori. Loju Ọrangun Meji ni. Ifa ni na lọ sọ bẹẹ, loju Ọrangun Meji abọru aboye. Naa Ifa sọ bẹẹ.Ofun Meji 1:This Ifa sign is Ọrangun Meji. If this sign comesup for someone, Ifa says (s)he is surrounded byenemies. (S)he should offer a sacrifice so that (s)he may defeat them. Ifa says (s)he will be victorious if (s)he offers a sacrifice. Ifa predictssuccess for this person. Ifa says his/her problem will become resolved and it will all come together, if this sign comes up in ỌrangunMeji. Ifa says so for this person. Ifa says (s)he should not be a miser. (S)He should be honest and open. If (s)he has money, (s)he should give some to others. (S)he should give to others. Ifa says this will make him/her victorious. (S)He should not be tightfisted. (S)he should be generous to others. Ifa says (s)he should be open, and (s)he will defeat his/her enemies. Yes, this is how Ifa said it:Ifa nla la nla fi gbafa nla n la, oogun nla nla laa figba oogun la nla. Ẹgbasere laa fi tanran Sere. Igba ta a ba ri Sere mọ, emi la fi tanran ẹ gba a, a difa fun Olokun nijọ ti ẹri gbogbo n ba ṣọta.[Powerful ifa must be used to resolve serious issues, a powerful medicine must be used to counter another powerful medicine. A fortune must be used to resolve Sere’s issue. What if we have no money, how will we resolve it? cast Ifa for Olokun when all of the bodies of water became her enemies.]All of the other bodies of water made Olokun their enemy. No matter what Olokun did, they would always find fault with it. They would not accept Olokun at all. She put two and two together and realized that she should go to see a babalawo. He said she could escape from the trouble in which she currently found herself, from all of those who had become her enemies.He cast Ifa about it. Ọrunmila told her, she could escape from the situation about which she was consulting Ifa. She would defeat all of her enemies and rule over all of them. That is what Ọrunmila’s divination revealed, and Olokunsaid it was so. Ọrunmila said she should offer a sacrifice of four female goats who have already had kids, lots of clothes, and lots of money and kola nuts. Ifa said once she had made a sacrifice with all of these, she would rule over all those who had become her enemies.Olokun offered the sacrifice and did everything required of her. She danced and rejoiced. When her victory was complete, all of the other bodiesof water came to her and said, “Ah Olokun, please, we are not your enemies anymore. Please forgive us!” All of them came begging for forgiveness. They came before her, every one of the rivers gathered there. They begged olokun for forgiveness. Olokun said she was not angry with them. She said she was not angry at all. She said, “All of you were angry withme. You were the ones who were fighting me, you were the ones who made an enemy out of me.” She was not angry. She praised the babalawo, and they in turn praised Ifa. She said, yes, my babalawo told me so, he said it would be so.Ifa nla la nla fi gbafa nla n la, oogun nla nla laa figba oogun la nla. Ẹgbasere laa fi tanran Sere. Igba ta a ba ri Sere mọ, emi la fi tanran ẹ gba a, a difa fun Olokun nijọ ti ẹri gbogbo n ba ṣọta.O ṣe bọwọ fun Olokun, omi mo gbọẸ bọwọ fun Olokun.Olokun lagba omi.Olokun lagba omi, Olokun lagba omi.Ẹri gbogbo, ẹri gbogbo ẹ bọwọ fun Olokun.Olokun lagba omi.Olokun lagba omi, Olokun lagba omi.Ẹri gbogbo ẹ bọwọ fun Olokun.Olokun lagba omi.[Powerful Ifa must be used to resolve serious issues, a powerful medicine must be used to counter another powerful medicine. A fortune must be used to resolve Sere’s issue. What if we have no money, how will we resolve it? cast Ifa for Olokun when all of the bodies of water became her enemies.O water, respect OlokunShow respect for OlokunOlokun is the ruler of all watersOlokun is the ruler of all watersOlokun is the ruler of all watersAll waters, all waters, respect OlokunOlokun is the head of all watersOlokun is the head of all watersOlokun is the head of all watersAll waters, show respect for OlokunOlokun is the ruler of all waters.]That is how Olokun [the ocean] became the leader of all bodies of water up until today. She is the ruler of all water. From that time, rivers submitted to her. She became their ruler. Ifa says this person should offer a sacrifice. (S)He will become the boss of all those who made an enemy of him/her. They will accept him/her as their leader. If this person wants to be a politician, or wants to occupy a certain position, Ifa says (s)he should offer a sacrifice. All of the people those conspiring against him, Ifa says (s)he will defeat all of them and become their boss. Yes, Ifa says so. If (s)he wants to be a governor, or a senator, or representative in the House of Reps, Ifa says (s)he will defeat them. Yes, this is what Ifa says in Ọrangun Meji.Ọrangun Meji 2:Ifa also says for this person in Ọrangun Meji that his/her issue will be resolved. Ifa predicts victory for this person. (S)He should be careful not to behave poorly. (S)He should be careful because anyone who will become successful requires prayer. A person who is not in a good way will require prayer. This person should be careful and watch his/her step so that (s)he doesn’t fall into temptation. (S)he shouldn’t be pompous. (S)He should not become full of him/herself because anyone who does so can be brought low at any time. Ifa says so, but if this person is careful, diligent in prayer, and hasbabalawo make medicine for him/her, (s)he will be victorious. Yes, this is how Ifa said it.Bi igi ba da, igi aiye ri, bi eniyan ba ku, a ku eniyan sa sa sa nile. Bi eni ori eni ba ku, eni ile le a si di eni ori eni a difa fun Araba pataki eyi ti o kẹhin igi loko.[When a branch falls of, another branch shoots up, when a person there will be others following. If the one on the throne dies, the one on the floor will move to the throne cast Ifa for the mature Silk Cotton Tree that outlives every other tree in the farm.]Araba [Silk Cotton Tree] was told to offer a sacrifice. It was surrounded by enemies. They were carefully plotting to kill it. Araba found out and offered the prescribed sacrifice. Araba was successful and defeated all of them. It said, “Ah,those babalawo who consulted Ifa for me, I must sing their praises.” So Araba went to tell them what had happened and to thank them. The priests in turn, took the kola nuts Araba hadbrought and gave some to Ifa. They danced andrejoiced. Araba said, yes my babalawo told me so, he said it would be so.Bi igi ba da, igi aiye ri, bi eniyan ba ku, a pe eniyan sa sa sa nile. Bi eni ori eni ba ku, eni ile le a si di eni ori eni a difa fun Araba pataki eyi ti o kẹhin igi loko. Ẹbọ ni wọn ni ko ṣe, o si gbe ẹbọ nibẹ, o rubọ. Riru ẹbọ ni fi ti gbe ni. Aitete ruteṣu a da ladanu. Ko pẹ, ko jinna, ifa wa ba ni la rin iṣẹgun, a rin iṣẹgun la ba ni lẹsẹ ọbariṣa.Oun ṣe: Kowo, kowo, Araba o wọ mọ.Oju ti roko. Ko kukuku mọ o.Otosi o ku mọ. Oju tọ lọrọ.Bi aiṣaiku sawo, ka ṣaiku sin awo,Eniyan ti n bawo yio dodi.Ka ṣaiku sawo…[When one branch falls off, another branch shoots up, when a person dies there will be others following. If the one on the throne dies, the one on the floor will move to the throne castIfa for the mature Silk Cotton Tree that outlives every other tree in the farm.They wanted to Araba to fall, but Araba did to fall.Iroko is ashamed. He didn’t die.If the poor person doesn’t die, the rich should be ashamed.Let us avoid death by following the priest.If you make an enemy of the priest, you are surely lost.]Ifa says every single person who has made an enemy out of this person will die. This person will reach the position (s)he desires and will be placed above all of them. Ifa says so in ỌrangunMeji..
Ọrangun Meji 2:
Ifa tun sọ fun eleyii, loju Ọrangun Meji [ba mi tilẹkun. Ah ah.] Ifa tun sọ fun eleyun loju Ọrangun Meji, Ifa ni ọran rẹ, yio gun, yio ko. Ifa ni, iṣẹgun n bẹ fun eleyii. Keleyii wa ṣọra. Ko ma siwa hu. Ko ṣọra, nitoripe eni to ba ti daa, ọran rẹ yio fadura. Ẹ n ti o da, ọran rẹ fadura. Keleyii oṣọra, ko ṣọ liẹtẹ. Ko ma ba ja sọfin aiye. Ko ma pe boun ṣe tore. Tori pe ẹ n ba ro pe bo n ṣe tore, anytime o le jabọ, ko dẹni lẹlẹ [that person becomes nothing]. Ifa na lọ sọ bẹẹ. Ifa ni ṣugbọn, teleyii ba ti ṣọra, to si mura ṣadura, tawọn babalawo si jawe Ifa fun un, Ifa ni iṣẹgun de. Bẹẹ ni, ibi Ifa un gba to fi sọ bẹẹ re o. O ni:Bi igi ba da, igi a yẹri, bi eniyan ba ku, a ku eniyan sa sa sa nilẹ. Bi eni ori eni ba ku, eni ilẹ le a si di eni ori eni a difa fun Araba pataki eyi ti o kẹhin igi loko.Wọn ni ki Araba, wọn ni o rubọ. Aarin ọta lo wa. Wọn mura ti ṣe ku pa papa ni. Laraba ba mọ, o gbọ riru, o ru. O ma gbọ titu, o tu. Iṣẹgun ba de. Laraba ba ṣẹgun, lo ṣẹgun, lo ba bori gbogbo wọn. Lo ni, ah , awọn babalawo tan dafa fun oun, o gbọdọ yin wọn. Lo ba sọ fun awọn awo rẹ. Lo lọ dupẹ. Nawọn awo naa, obi to mu wa sọdọ awo, awo naa mu lọ nifa. Na nan ba n jo, nan yọ. O ni bẹẹ babalawo toun [wi] bẹẹ, babalawo toun sọ.Bi igi ba da, igi aiye ri, bi eniyan ba ku, a pe eniyan sa sa sa nilẹ. Bi eni ori eni ba ku, eni ilẹ le a si di eni ori eni a difa fun Araba pataki eyi ti o kẹhin igi loko. Ẹbọ ni wọn ni ko ṣe, o si gbe ẹbọ nibẹ, o rubọ. Riru ẹbọ ni fi ti gbe ni. Aitete ruteṣu a da ladanu. Ko pẹ, ko jinna, Ifa wa ba ni la rin iṣẹgun, a rin iṣẹgun la ba ni lẹsẹ ọbariṣa.Oun ṣe: Kowo, kowo, Araba o wo mọ.Oju tiroko. Ko kukuku mọ o, otoṣi o ku mọ. Oju tọ lọrọ. Bi aiṣaiku sawo, ka ṣaiku sin awo, eniyanti n bawo yan odi.Ka ṣaiku sawo…Ifa ni gbogbo eni ba ba eleyun ṣọta patapata, ni o ku danu patapata. Teleyun o si depo ibi ti n lọ, ti o dolori le wọn lori. Loju Ọrangun Meji ni. Ifa ni na lọ sọ bẹẹ, loju Ọrangun Meji abọru aboye. Naa Ifa sọ bẹẹ.
Translation
Ofun Meji 1:
This Ifa sign is Ọrangun Meji. If this sign comesup for someone, Ifa says (s)he is surrounded byenemies. (S)he should offer a sacrifice so that (s)he may defeat them. Ifa says (s)he will be victorious if (s)he offers a sacrifice. Ifa predictssuccess for this person. Ifa says his/her problem will become resolved and it will all come together, if this sign comes up in ỌrangunMeji. Ifa says so for this person. Ifa says (s)he should not be a miser. (S)He should be honest and open. If (s)he has money, (s)he should give some to others. (S)he should give to others. Ifa says this will make him/her victorious. (S)He should not be tightfisted. (S)he should be generous to others. Ifa says (s)he should be open, and (s)he will defeat his/her enemies. Yes, this is how Ifa said it:Ifa nla la nla fi gbafa nla n la, oogun nla nla laa figba oogun la nla. Ẹgbasere laa fi tanran Sere. Igba ta a ba ri Sere mọ, emi la fi tanran ẹ gba a, a difa fun Olokun nijọ ti ẹri gbogbo n ba ṣọta.[Powerful ifa must be used to resolve serious issues, a powerful medicine must be used to counter another powerful medicine. A fortune must be used to resolve Sere’s issue. What if we have no money, how will we resolve it? cast Ifa for Olokun when all of the bodies of water became her enemies.]All of the other bodies of water made Olokun their enemy. No matter what Olokun did, they would always find fault with it. They would not accept Olokun at all. She put two and two together and realized that she should go to see a babalawo. He said she could escape from the trouble in which she currently found herself, from all of those who had become her enemies.He cast Ifa about it. Ọrunmila told her, she could escape from the situation about which she was consulting Ifa. She would defeat all of her enemies and rule over all of them. That is what Ọrunmila’s divination revealed, and Olokunsaid it was so. Ọrunmila said she should offer a sacrifice of four female goats who have already had kids, lots of clothes, and lots of money and kola nuts. Ifa said once she had made a sacrifice with all of these, she would rule over all those who had become her enemies.Olokun offered the sacrifice and did everything required of her. She danced and rejoiced. When her victory was complete, all of the other bodiesof water came to her and said, “Ah Olokun, please, we are not your enemies anymore. Please forgive us!” All of them came begging for forgiveness. They came before her, every one of the rivers gathered there. They begged olokun for forgiveness. Olokun said she was not angry with them. She said she was not angry at all. She said, “All of you were angry withme. You were the ones who were fighting me, you were the ones who made an enemy out of me.” She was not angry. She praised the babalawo, and they in turn praised Ifa. She said, yes, my babalawo told me so, he said it would be so.Ifa nla la nla fi gbafa nla n la, oogun nla nla laa figba oogun la nla. Ẹgbasere laa fi tanran Sere. Igba ta a ba ri Sere mọ, emi la fi tanran ẹ gba a, a difa fun Olokun nijọ ti ẹri gbogbo n ba ṣọta.O ṣe bọwọ fun Olokun, omi mo gbọẸ bọwọ fun Olokun.Olokun lagba omi.Olokun lagba omi, Olokun lagba omi.Ẹri gbogbo, ẹri gbogbo ẹ bọwọ fun Olokun.Olokun lagba omi.Olokun lagba omi, Olokun lagba omi.Ẹri gbogbo ẹ bọwọ fun Olokun.Olokun lagba omi.[Powerful Ifa must be used to resolve serious issues, a powerful medicine must be used to counter another powerful medicine. A fortune must be used to resolve Sere’s issue. What if we have no money, how will we resolve it? cast Ifa for Olokun when all of the bodies of water became her enemies.O water, respect OlokunShow respect for OlokunOlokun is the ruler of all watersOlokun is the ruler of all watersOlokun is the ruler of all watersAll waters, all waters, respect OlokunOlokun is the head of all watersOlokun is the head of all watersOlokun is the head of all watersAll waters, show respect for OlokunOlokun is the ruler of all waters.]That is how Olokun [the ocean] became the leader of all bodies of water up until today. She is the ruler of all water. From that time, rivers submitted to her. She became their ruler. Ifa says this person should offer a sacrifice. (S)He will become the boss of all those who made an enemy of him/her. They will accept him/her as their leader. If this person wants to be a politician, or wants to occupy a certain position, Ifa says (s)he should offer a sacrifice. All of the people those conspiring against him, Ifa says (s)he will defeat all of them and become their boss. Yes, Ifa says so. If (s)he wants to be a governor, or a senator, or representative in the House of Reps, Ifa says (s)he will defeat them. Yes, this is what Ifa says in Ọrangun Meji.
Orangun Meji 2
Ifa also says for this person in Ọrangun Meji that his/her issue will be resolved. Ifa predicts victory for this person. (S)He should be careful not to behave poorly. (S)He should be careful because anyone who will become successful requires prayer. A person who is not in a good way will require prayer. This person should be careful and watch his/her step so that (s)he doesn’t fall into temptation. (S)he shouldn’t be pompous. (S)He should not become full of him/herself because anyone who does so can be brought low at any time. Ifa says so, but if this person is careful, diligent in prayer, and hasbabalawo make medicine for him/her, (s)he will be victorious. Yes, this is how Ifa said it.Bi igi ba da, igi aiye ri, bi eniyan ba ku, a ku eniyan sa sa sa nile. Bi eni ori eni ba ku, eni ile le a si di eni ori eni a difa fun Araba pataki eyi ti o kẹhin igi loko.[When a branch falls of, another branch shoots up, when a person there will be others following. If the one on the throne dies, the one on the floor will move to the throne cast Ifa for the mature Silk Cotton Tree that outlives every other tree in the farm.]Araba [Silk Cotton Tree] was told to offer a sacrifice. It was surrounded by enemies. They were carefully plotting to kill it. Araba found out and offered the prescribed sacrifice. Araba was successful and defeated all of them. It said, “Ah,those babalawo who consulted Ifa for me, I must sing their praises.” So Araba went to tell them what had happened and to thank them. The priests in turn, took the kola nuts Araba hadbrought and gave some to Ifa. They danced andrejoiced. Araba said, yes my babalawo told me so, he said it would be so.Bi igi ba da, igi aiye ri, bi eniyan ba ku, a pe eniyan sa sa sa nile. Bi eni ori eni ba ku, eni ile le a si di eni ori eni a difa fun Araba pataki eyi ti o kẹhin igi loko. Ẹbọ ni wọn ni ko ṣe, o si gbe ẹbọ nibẹ, o rubọ. Riru ẹbọ ni fi ti gbe ni. Aitete ruteṣu a da ladanu. Ko pẹ, ko jinna, ifa wa ba ni la rin iṣẹgun, a rin iṣẹgun la ba ni lẹsẹ ọbariṣa.Oun ṣe: Kowo, kowo, Araba o wọ mọ.Oju ti roko. Ko kukuku mọ o.Otosi o ku mọ. Oju tọ lọrọ.Bi aiṣaiku sawo, ka ṣaiku sin awo,Eniyan ti n bawo yio dodi.Ka ṣaiku sawo…[When one branch falls off, another branch shoots up, when a person dies there will be others following. If the one on the throne dies, the one on the floor will move to the throne castIfa for the mature Silk Cotton Tree that outlives every other tree in the farm.They wanted to Araba to fall, but Araba did to fall.Iroko is ashamed. He didn’t die.If the poor person doesn’t die, the rich should be ashamed.Let us avoid death by following the priest.If you make an enemy of the priest, you are surely lost.]Ifa says every single person who has made an enemy out of this person will die. This person will reach the position (s)he desires and will be placed above all of them. Ifa says so in ỌrangunMeji.


Spanish Version

Esta redacción fue compilada por el omo Awo Rodriguez Ifatomi y un aprendiz ifa bajo la tutela de babalawo Obanifa.

ODU IFA OSE MEJI:

I  I

II II

I. I

II II

Ọsẹ Meji 1:


Ifa a wa nlẹ yii, Ọsẹ Meji lo wa nlẹ yii. Ifa sọ diversión eleyii wipe ara ọrọọ [no confortable], ninu ipọnju lo wa. Ifa ni ko rubọ, Ifa ni yio ṣegun ti gbogbo ibi, iṣẹlẹ buruku ti n σẹlẹ si i, ainiṣiwaju, airitajeṣe, Ifa ni gbogbo ẹ yio dẹrọ [calmar]. Ti ayipada yio de baa, ti o si ri ta jeṣe, loju Ọsẹ Meji. Bifa na fi sọ bẹẹ ni diversión eleyii. O ni: Igba abidi jẹgi arugbo eti emi, atori abidi gbadagi un dia divertido Ọrunmila, baba n ṣe awo montó Irọ. Ifa jẹ [ki] ara o rọ mi, akasu mẹfa nirọ fi rọ ni.Ọrunmila jẹ [ki] ara o rọ mi.Ifa lara o rọ eleyii ko rubọ nbẹ loju Ọsẹ Meji. Ifa ... Ifa ... Ifa ni o maa ... ara maa rọ, ma ri ta je ṣe. Ọna rẹ maa la nbẹ. Ifa na sọ bẹẹ loju Ọsẹ Meji. Niña

Ọsẹ Meji 2:

Ifa yii si tun sọ diversión eleyii limpiar, aarin ọta lo wa. Ko si rubọ, ko bọ ori rẹ. Ifa ni iṣẹgun o wa fun un. Gbogbo awọn tan ba ṣe ọta oun pata, Ifa lẹlẹda rẹ yio ... yio ... yio ṣe wọn ti o pa wọn jẹ danuni. Gbogbo awọn eni ti wọn ba ṣọta yio ku danu ni. Ifa un lo sọ bẹẹ. Enikan [k] ii ba babalawo ṣọta. Ifa ni keleyii ni obi, ko lobi lẹbọ nbẹ. Kan bapabi sifa nbẹ. Gbogbo awọn tan ba ṣọta, Ifa ni wọn o ku danu ni. Bẹẹ ni, Ifa sọ ninu Ọsẹ Meji. Nibi Ifa gba to fi sọ bẹẹ. O ni: Olori ni yanri, ogbẹri o gbọdọ gba obi pa lọ babalawo una difa diversión Ọsẹ ti o ṣẹgun laiye ti o si ṣẹgun lajule ọrun.Wọn ni ki Ọsẹ Meji wọn ni ... ko rubọ o. Aarin ọta lo wa. Lọsẹ Meji ba rubọ, lo ba ṣẹgun awọn ọta rẹ. Ni n ba jo ni n ba n yọ. O ni bẹẹ babalawo toun [wi] bẹẹ, babalawo toun sọ.Olori ni yanri o, ogbẹri o gbọdọ gba obi pa lọwọ babalawo una difa diversión Ọsẹ ti o ṣẹgun laiye ti o si ṣẹgun lajule ọrun. Ero Epo, ero Ọffa, ẹyin o rifa ọjọ bi ti n ṣẹ.Bi gbogbo awọn ọta ẹ ṣe ku nu un. Ifa ni eleyun yio ṣẹgun ọta. Gbogbo awọn ọta ẹ yio ku danu loju Ọsẹ Meji. Niña Ifa sọ bẹẹ.

Ọsẹ Meji 3:

Ifa tun wa tẹ mọ eleyii leti, oun sọ diversión eleyii, o laṣeyọri wa fun o. Ifa ni eleyii n viajar lọ bi kan. O lọ ilu odikeji. O fẹ gbiyanju lo nipa ọrọ aje, nipa son gbogbo. Ifa ni ko ṣetutu, ko ma lọ. Ibi ton lio y gba a. Ti o dọlọla, ti o dẹlẹni, ti o donire gbogbo. Para j o pe alejo o tun ma de ba, ti o lagbo gan, tagbo rẹ o fẹ. Ifa ni ko ṣetutu nbẹ. Bẹẹ ni loju Ọsẹ Meji. Ifa ti sọ bẹẹ diversión eleyii, ko ma lọ, o ni [k] o ṣetutu. Bo ba jẹ pe oko waju lo n lọ, ko lọ, ko lọ mẹgan. Yio ṣaṣeyọri nbẹ. Yio da ile a lẹ, ti gbogbo eniyan maa ... eniyan maa ba gbe. Si bien la empresa es la empresa de la sociedad, Ifa ni to ba ti daalẹ tan, yio yio loluranlọwọ nbẹ, ti gbogbo eniyan yio tun wa funcionó un lọwọ nbẹ. Ti o niyawo, ti o bimọ, ti o nire gbogbo, ti o gbọsin, ti o gbọra. Bẹẹ ni, Ọsẹ Meji lo sọ bẹẹ. Ifa na sọ pe: Olori ni yan ori, ogbẹri o gbọdọ gba obi pa lọwọ babalawo una difa diversión Ọsẹ ni ọjọ ti n ṣe awo cabalgaron Ibadan.Wọn ni, ibi to n lọ .... Yio si gbọsi, yio si gbọra, yio nire gbogbo. Ọsẹ Meji ba, lo ba ṣetutu, lo gbọna Ibadan. Bọsẹ Meji si gbọsi, to gbọra nu un. Lo labu [éxito], lo la yẹbyẹbẹ. Lọran ẹ gun, lo ko, ni n yin awọn awo, la ley de awo wa n yin Ifa. O ni bẹẹ, gẹgẹ ni babalawo toun wi, babalawo toun sọ.Olori ni yan ori, ogbẹri o gbọdọ gba obi pa lọwọ babalawo difa diversión Ọsẹ ni ọjọ ti n ṣe awo cabalgar Ibadan. Ẹbọ ni wọn ni o ṣe, ero Epo, ero Ọffa, ẹ wa ba ni jẹbutu ire. Jẹbutu ire, la ba ni lẹsẹ ọbariṣa. Ero Epo, ero Ọffa, ẹ wa ba ni ni jẹbutu ọmọ, jẹbutu ọmọ, la ba ni lẹsẹ ọbariṣa. Jẹbutu aya, la ba ni lẹsẹ ọbariṣa.Ifa ni keleyun o rubọ; Ifa laṣeyọri wa diversión un, ti o labu, ti o si sẹgun ọta rẹ. Bẹẹ ni Ifa sọ nu loju Ọsẹ Meji. Abọru aboye. Tifa na sọ nu

TRADUCCIÓN

Ọsẹ Meji 1:





No comments:

Post a Comment

Note: Only a member of this blog may post a comment.

Featured post

Work-Life Balance - How to Protect Your Boundaries When Your Company Is Struggling - Sun and Planets Spirituality AYINRIN

 Work-Life Balance -  How to Protect Your Boundaries When Your Company Is Struggling - Sun and Planets Spirituality AYINRIN HBR Staff/Unspla...